Orin Dafidi 36:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ga kan ọ̀run;òtítọ́ rẹ sì kan ojú ọ̀run.

Orin Dafidi 36

Orin Dafidi 36:1-12