Orin Dafidi 36:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé lọ́kàn rẹ̀ a máa pọ́n ara rẹ̀,pé kò sí ẹni tí ó lè rí ẹ̀ṣẹ̀ òun,ká tó wá sọ pé yóo dá òun lẹ́bi.

Orin Dafidi 36

Orin Dafidi 36:1-9