Orin Dafidi 36:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Má jẹ́ kí àwọn agbéraga borí mi,má sì jẹ́ kí àwọn eniyan burúkú lé mi kúrò.

Orin Dafidi 36

Orin Dafidi 36:4-12