Orin Dafidi 35:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ìparun dé bá wọn lójijì,jẹ́ kí àwọ̀n tí wọ́n dẹ sílẹ̀ dè mí mú wọn;jẹ́ kí wọ́n kó sinu rẹ̀, kí wọ́n sì parun!

Orin Dafidi 35

Orin Dafidi 35:1-12