Orin Dafidi 35:17 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, yóo ti pẹ́ tó, tí o óo máa wò mí níran?Yọ mí kúrò ninu ogun tí wọn gbé tì mí,gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn kinniun!

Orin Dafidi 35

Orin Dafidi 35:10-22