Orin Dafidi 35:14 BIBELI MIMỌ (BM)

bí ẹni pé mò ń ṣọ̀fọ̀ ọ̀rẹ́ mi, tabi arakunrin mi;mò ń lọ káàkiri, bí ẹni tí ń pohùnréré ẹkún ìyá rẹ̀,mo doríkodò, mo sì ń ṣọ̀fọ̀.

Orin Dafidi 35

Orin Dafidi 35:8-19