Orin Dafidi 35:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA, gbógun ti àwọn tí ń gbógun tì mí;gbé ìjà ko àwọn tí ń bá mi jà!

2. Gbá asà ati apata mú,dìde, kí o sì ràn mí lọ́wọ́!

Orin Dafidi 35