Orin Dafidi 34:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Olùpọ́njú ké pe OLUWA, OLUWA gbọ́ ohùn rẹ̀,ó sì gbà á ninu gbogbo ìpọ́njú rẹ̀.

Orin Dafidi 34

Orin Dafidi 34:1-12