Orin Dafidi 34:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣọ́ ẹnu yín, ẹ má sọ̀rọ̀ burúkú,ẹ má sì jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹ̀tàn ti ẹnu yín jáde.

Orin Dafidi 34

Orin Dafidi 34:9-14