Orin Dafidi 32:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí n kò jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ mi,ó rẹ̀ mí wá láti inú,nítorí kíkérora tí mò ń kérora ní gbogbo ìgbà.

Orin Dafidi 32

Orin Dafidi 32:1-8