Orin Dafidi 31:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo máa yọ̀, inú mi óo sì máa dùn,nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀;nítorí pé o ti rí ìpọ́njú mi,o sì mọ ìṣòro mi.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:6-17