Orin Dafidi 31:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Yọ mí kúrò ninu àwọ̀n tí wọ́n dẹ pamọ́ dè mí,nítorí ìwọ ni ẹni ìsádi mi.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:1-8