Orin Dafidi 31:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìgbà mi ń bẹ ní ọwọ́ rẹ;gbà mí lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi,ati lọ́wọ́ àwọn tí ń lépa mi.

Orin Dafidi 31

Orin Dafidi 31:5-18