Orin Dafidi 30:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nípa ojurere rẹ, OLUWA,o ti fi ìdí mi múlẹ̀ bí òkè ńlá;ṣugbọn nígbà tí o fi ojú pamọ́ fún mi,ìdààmú dé bá mi.

Orin Dafidi 30

Orin Dafidi 30:1-9