Orin Dafidi 27:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nisinsinyii n óo ní ìṣẹ́gunlórí àwọn ọ̀tá mi tí ó yí mi ká;n óo rúbọ ninu àgọ́ rẹ̀ pẹlu ìhó ayọ̀,n óo sì kọ orin aládùn sí OLUWA.

Orin Dafidi 27

Orin Dafidi 27:1-13