Orin Dafidi 26:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Dá mi láre, OLUWA,nítorí ninu ìwà pípé ni mò ń rìn,mo sì gbẹ́kẹ̀lé OLUWA láìṣiyèméjì.

Orin Dafidi 26

Orin Dafidi 26:1-10