Orin Dafidi 25:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Má ranti ẹ̀ṣẹ̀ tí mo ti ṣẹ̀ ní ìgbà èwe mi,tabi ibi tí mo ti kọjá ààyè mi;ranti mi, OLUWA, nítorí ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀,ati nítorí oore rẹ.

Orin Dafidi 25

Orin Dafidi 25:1-15