Orin Dafidi 25:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pípé mi ati òdodo mi, pa mí mọ́,nítorí pé ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé.

Orin Dafidi 25

Orin Dafidi 25:16-22