Orin Dafidi 23:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Dájúdájú, ire ati àánú yóo máa tẹ̀lé mi kiri,ní gbogbo ọjọ́ ayé mi;èmi óo sì máa gbé inú ilé OLUWA laelae.

Orin Dafidi 23

Orin Dafidi 23:4-6