Orin Dafidi 23:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Àní, bí mo tilẹ̀ ń rìn ninu òkùnkùn létí bèbè ikú,n kò ní bẹ̀rù ibi kankan;nítorí tí o wà pẹlu mi;ọ̀gọ rẹ ati ọ̀pá rẹ ń fi mí lọ́kàn balẹ̀.

Orin Dafidi 23

Orin Dafidi 23:1-6