Orin Dafidi 22:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Agbára mi ti lọ, ó ti ṣàn dànù bí omi,gbogbo egungun mi ti yẹ̀ lóríkèéríkèé;ọkàn mi dàbí ìda, ó ti yọ́.

Orin Dafidi 22

Orin Dafidi 22:4-20