Orin Dafidi 22:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọlọrun mi, Ọlọrun mi, kí ló dé tí o fi kọ̀ mí sílẹ̀,tí o fi jìnnà sí mi, tí o kò gbọ́ igbe mi,kí o sì ràn mí lọ́wọ́?

Orin Dafidi 22

Orin Dafidi 22:1-5