Orin Dafidi 21:1 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọba ń yọ̀ nítorí agbára rẹ, OLUWA;inú rẹ̀ ń dùn lọpọlọpọ nítorí ríràn tí o ràn án lọ́wọ́!

Orin Dafidi 21

Orin Dafidi 21:1-8