Orin Dafidi 2:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo kéde ohun tí OLUWA pa láṣẹ ní ti èmi ọba;Ó wí fún mi pé, “Ìwọ ni ọmọ mi,lónìí ni mo bí ọ.

Orin Dafidi 2

Orin Dafidi 2:2-12