Orin Dafidi 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn náà, yóo sọ̀rọ̀ sí wọn ninu ibinu rẹ̀,yóo dẹ́rùbà wọ́n gidigidi ninu ìrúnú rẹ̀,

Orin Dafidi 2

Orin Dafidi 2:1-8