Orin Dafidi 2:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, ẹ̀yin ọba, ẹ kọ́gbọ́n;ẹ̀yin onídàájọ́ ayé, ẹ gba ìkìlọ̀.

Orin Dafidi 2

Orin Dafidi 2:1-12