Orin Dafidi 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Láti apá kan ojú ọ̀run ni ó ti ń yọ wá,a máa yípo gbogbo ojú ọ̀run dé apá keji;kò sì sí ohun tí ó bọ́ lọ́wọ́ ooru rẹ̀.

Orin Dafidi 19

Orin Dafidi 19:1-7