Orin Dafidi 19:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ ẹnu mi, ati àṣàrò ọkàn mijẹ́ ìtẹ́wọ́gbà ní ojú rẹ,OLUWA ibi ààbò mi ati olùràpadà mi.

Orin Dafidi 19

Orin Dafidi 19:8-14