Orin Dafidi 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wuni ju wúrà lọ,àní ju ojúlówó wúrà lọ;wọ́n sì dùn ju oyin,àní, wọ́n dùn ju oyin tí ń kán láti inú afárá lọ.

Orin Dafidi 19

Orin Dafidi 19:4-14