Orin Dafidi 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ìpọ́njú mi mo ké pe OLUWA,Ọlọrun mi ni mo ké pè.Ó gbọ́ ohùn mi láti inú ilé mímọ́ rẹ̀,ó sì tẹ́tí sí igbe mi.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:1-16