Orin Dafidi 18:39 BIBELI MIMỌ (BM)

O gbé agbára ogun wọ̀ mí;o sì mú àwọn tí ó dìde sí mi wólẹ̀ lábẹ́ ẹsẹ̀ mi.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:34-48