Orin Dafidi 18:35 BIBELI MIMỌ (BM)

O ti fún mi ní asà ìgbàlà rẹ,ọwọ́ ọ̀tún rẹ ni ó gbé mi ró,ìrànlọ́wọ́ rẹ sì ni ó sọ mí di ẹni ńlá.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:28-42