Orin Dafidi 18:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà ni OLUWA ṣe san án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi;ati gẹ́gẹ́ bí ọwọ́ mi ṣe mọ́ lójú rẹ̀.

Orin Dafidi 18

Orin Dafidi 18:19-32