Orin Dafidi 17:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Yẹ ọkàn mi wò; bẹ̀ mí wò lóru.Dán mi wò, o kò ní rí ohun burúkú kan;n kò ní fi ẹnu mi dẹ́ṣẹ̀.

Orin Dafidi 17

Orin Dafidi 17:1-5