Orin Dafidi 150:1-3 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ẹ yin OLUWA!Ẹ yin Ọlọrun ninu ibi mímọ́ rẹ̀;ẹ yìn ín ninu òfuurufú rẹ̀ tí ó lágbára.

2. Ẹ yìn ín fún iṣẹ́ ńlá rẹ̀;ẹ yìn ín nítorí pé ó tóbi pupọ.

3. Ẹ fi ariwo fèrè yìn ín;ẹ fi fèrè ati hapu yìn ín.

Orin Dafidi 150