Orin Dafidi 149:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí pé inú OLUWA dùn sí àwọn eniyan rẹ̀,a sì máa fi ìṣẹ́gun dé àwọn onírẹ̀lẹ̀ ládé.

Orin Dafidi 149

Orin Dafidi 149:1-7