Orin Dafidi 147:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó pàṣẹ lórí ilẹ̀ ayé,àṣẹ rẹ̀ sì múlẹ̀ kíá.

Orin Dafidi 147

Orin Dafidi 147:6-17