Orin Dafidi 147:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Kì í ṣe agbára ẹṣin ni inú rẹ̀ dùn sí,kì í sì í ṣe inú agbára eniyan ni ayọ̀ rẹ̀ wà.

Orin Dafidi 147

Orin Dafidi 147:1-16