Orin Dafidi 146:7 BIBELI MIMỌ (BM)

ẹni tíí máa ń dá ẹjọ́ òdodo fún àwọn tí a ni lára;tí ń fún àwọn tí ebi ń pa ní oúnjẹ,OLUWA tíí tú àwọn tí ó wà ninu ìdè sílẹ̀.

Orin Dafidi 146

Orin Dafidi 146:1-10