Orin Dafidi 145:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Eniyan óo máa kéde iṣẹ́ agbára rẹ tí ó yani lẹ́nu,èmi óo sì máa polongo títóbi rẹ.

Orin Dafidi 145

Orin Dafidi 145:1-12