Orin Dafidi 145:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA súnmọ́ gbogbo àwọn tí ń pè é,àní, àwọn tí ń pè é tọkàntọkàn.

Orin Dafidi 145

Orin Dafidi 145:14-21