Orin Dafidi 145:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìjọba ayérayé ni ìjọba rẹ,yóo sì máa wà láti ìran dé ìran.Olóòótọ́ ni OLUWA ninu gbogbo ọ̀rọ̀ rẹ̀,olóore ọ̀fẹ́ sì ni ninu gbogbo ìṣe rẹ̀.

Orin Dafidi 145

Orin Dafidi 145:3-17