Orin Dafidi 145:10 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, gbogbo ohun tí o dá ni yóo máa dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ,àwọn eniyan mímọ́ rẹ yóo sì máa yìn ọ́.

Orin Dafidi 145

Orin Dafidi 145:9-18