Orin Dafidi 144:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Òun ni àpáta mi, ààbò mi, odi mi, olùdáǹdè mi,asà mi, ẹni tí mo sá di.Òun ni ó tẹrí àwọn eniyan ba lábẹ́ rẹ̀.

Orin Dafidi 144

Orin Dafidi 144:1-8