Orin Dafidi 143:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jẹ́ kí n máa ranti ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ láràárọ̀,nítorí ìwọ ni mo gbẹ́kẹ̀lé.Kọ́ mi ní ọ̀nà tí n óo máa rìn,nítorí pé ìwọ ni mo gbójú sókè sí.

Orin Dafidi 143

Orin Dafidi 143:1-12