Orin Dafidi 142:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbọ́ igbe mi;nítorí wọ́n ti rẹ̀ mí sílẹ̀ patapata.Gbà mí lọ́wọ́ àwọn tí ń ṣe inúnibíni mi,nítorí pé wọ́n lágbára jù mí lọ.

Orin Dafidi 142

Orin Dafidi 142:1-7