Orin Dafidi 140:4 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA, ṣọ́ mi lọ́wọ́ àwọn eniyan burúkú;dáàbò bò mí lọ́wọ́ àwọn oníwà ipá,tí ó ń gbìmọ̀ láti ré mi lẹ́pa.

Orin Dafidi 140

Orin Dafidi 140:1-12