Orin Dafidi 139:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Níbo ni mo lè sá lọ, tí ẹ̀mí rẹ kò ní sí níbẹ̀?Níbo ni mo lè sá gbà tí ojú rẹ kò ní tó mi?

Orin Dafidi 139

Orin Dafidi 139:2-15