Orin Dafidi 139:5 BIBELI MIMỌ (BM)

O pa mí mọ́, níwájú ati lẹ́yìn;o gbé ọwọ́ ààbò rẹ lé mi.

Orin Dafidi 139

Orin Dafidi 139:1-14