Orin Dafidi 137:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Lẹ́bàá odò Babiloni ni a jókòó, tí a sọkún,nígbà tí a ranti Sioni.

2. Lára igi wilo níbẹ̀ ni a fi hapu wa kọ́ sí,

Orin Dafidi 137